| Question | Options | Answer |
|---|---|---|
| YORUBA JSS 1: Labẹ igi orombo ti o wa lẹba igi agbalumọ ni Tọla, Yẹmi ati Kemi ti n ṣe ere bojuboju. Ere okoto tita ni won kọkọ ṣe ṣugbọn ere okun mẹran ni won fẹ ṣe ti Iya won Amina fi de lati ọja Ifọ. Awon ọmọde wonyii ṣere idaraya ti won n ṣe ti lati lọ ki Iya won kaaba. Inu Iya won dun nitori pe awon ọmọ naa ti pari isẹ ile ti o yan fun ọkọọkan wọn. O mu ileri rẹ ṣẹ nipa fifun awọn ọmọ naa ni nnkan abọ ti o ra fun wọn. Inu wọn dun, Tọla ati Yemi dọbalẹ nigba ti Kẹmi kunlẹ. Awon ọmọ naa |
A) agbalumọ B) ọsan C) rọba D) kaṣu |
optionA |
| Ere idaraya ti awon ọmọ naa kọkọ ṣe ni ere _____ |
A) okoro tita B) bojujboju C) okun meran D) ludo |
optionB |
| Ere idaraya ti won fẹ ṣe nigba ti Amina de ni |
A) bojuboju B) okun meran C) okoto tita D) ayo ọlọpọn |
optionB |
| _____ ni Iya awon omo naa |
A) Tola B) Kemi C) Amina D) Yemi |
optionC |
| Ki ni idi ti inu Iya awon omo naa se dun si won? |
A) wọn ṣe iṣẹ ile B) won se ere idaraya C) won n ja D) won wa labẹ igi orombo |
optionA |
| Ọrọ orukọ ti a ko ṣẹda ni |
A) ọlọ B) ijokoo C) aja D) ounjẹ |
optionC |
| Orisii Litireso meloo ni o wa? |
A) ikan B) meji C) meta D) merin |
optionB |
| Oro oruko ti a seda nipa afomọ aarin ni |
A) oṣooṣu B) ọsọọsẹ C) ọmọkọmọ D) iyaale |
optionA |
| Ewi alohun ajẹmayẹyẹ ni |
A) Orin oro B) ẹrẹ ifa C) Ogun pipe D) bọlọjọ |
optionD |
| Litireso wulo fun |
A) idaraya B) orin C) ijo D) orun sisun |
optionA |
| '45' ni ede Yoruba ni |
A) aarunlelogorun B) eerindinlogoji C) aarunlelogoji D) eerindin laadọta |
optionC |
| Ọrọ orukọ ti a ṣẹda ni |
A) igbalẹ B) orin C) iwe D) baba |
optionA |
| A ṣẹda "alaṣọ" nipa lilo |
A) afomọ ẹyin B) afomọ aarin C) apetunpe D) afomọ ibẹrẹ 'oni' |
optionD |
| "Ẹẹtalelọgbọn" jẹ |
A) 43 B) 33 C) 23 D) 53 |
optionB |
| A ṣẹda "ọmọkọmọ" nipa lilo |
A) apetunpe B) afomọ aarin C) afomọ iwaju D) afomọ ẹyin |
optionB |
| Ilu to n lo "Dadakuada" ni |
A) Ọyọ B) Egba C) Ẹgbado D) Ilorin |
optionD |
| Awọn ______ lo n sun Iyẹrẹ |
A) babalawo B) ọlọya C) eleṣu D) oloro |
optionA |
| "Noun" ni ede Yoruba ni |
A) ọrọ orukọ B) ọrọ iṣe C) ọrọ apọnle D) asopọ |
optionA |
| "Verb" ni ede Yoruba ni |
A) ọrọ orukọ B) ọrọ iṣe C) ọrọ aponle D) ete onise |
optionB |
| Ọrọ orukọ aṣeeka ni |
A) iyẹpẹ B) elubọ C) omi D) tabili |
optionD |
| JSS TWO YORUBA: Ni ọjọ kan, Funke wa ni ile epo nibi ti o ti n sise yii, ti o si n ta epi fun awon onimọto ni ọkọkan, ejeeji. Ni ojiji ni awon igaraọlọṣa t'awọn ti ibọn lọwọ ya wọ ile epo ibi ti Funkẹ ti n ṣiṣẹ. Afi Kosa!, kosa! kosa! ti wọn da ibọn bolẹ. Ọrọ do boolọ o pagoda lọna. Gbogbo awọn ti wọn paaki lati ra epo bẹ silẹ ninu mọto, wọn si n salọ, lati sa asala fun ẹmi wọn. Mo n gbọ "Doju ẹ delẹ, doju e delẹ" bẹẹ ni wọn n yin ibọn soke kosa kosa. Logan ni awọn eniyan bii mẹfa ti fara gba |
A) awon ota wa B) awon ole wa C) awon olopa wa D) awon olukowa |
optionA |
| Ki ni awon onibara ti won gbo iro ibon se? |
A) won sa fun emi ara won B) won dojuko awon ole na C) won gba ibon lowo awon ole D) won salo si odo awon olopa |
optionA |
| Ki lo sele si awon meta ti won ku? |
A) ota ibon ba won B) aja ke won je C) omi pa won D) ijamba ina lo pa won |
optionA |
| Ki ni idi ti won fi ta Funke ni kokosẹ? |
A) n lọ tikọtikọ B) o mbe awon ole na C) o feran won lopolopo D) ko mo ouhn to nsele |
optionA |
| Awon wo ni won gba owo lọwọ awon eniyan? |
A) funke B) onibara C) ile epo D) ole |
optionD |
| Awon wo ni won n kigbe ole, ole, oleee nigba ti awon ole lọ tan? |
A) awon olopa B) funke C) awon eniyan ile epo D) atedanti |
optionC |
| Igbe wo ni Funke n ke nigba ti o wa ninu ẹjẹ ara rẹ? |
A) e jowo e bami pa awon ole yi B) ẹ jọwọ, ẹgba mi o, e ma je n ku bayii C) e jowo e bami gba owo mi D) e jowo e bami mu won |
optionB |
| Igbe wo ni awon ole pa bi won ti wọ ile epo? |
A) e jade sita eyin eniyan B) e wa bami ja C) e doju bole D) e tan epo fun wa |
optionC |
| Orukọ miiran ti won pe "awon ole" ninu ayoka oke ni |
A) funke B) igaraolosa C) olopa D) atedanti |
optionB |
| Bawo ni ibon awon ole se n fun? |
A) kosa kosa B) koya koya C) kosekose D) kolokolo |
optionA |
| Awon ilu to maa n kọ OBITUN ni |
A) Ọyọ B) Ekiti C) Egba D) Ondo |
optionA |
| ______ lo maa n ṣiwaju ijo |
A) Orin B) Ẹkun C) Ilu D) Ayọ |
optionB |
| Awon ______ lo maa n sun IYẸRẸ |
A) eleegun B) onifa C) eleṣu D) oniwaasu |
optionB |
| ______ jẹ apẹrẹ ijo ibile |
A) Hip-hop B) Makosa C) Bata D) yahuse |
optionC |
| __ je a)Isare ajemẹsin |
A) ijala B) babalawo C) Ogun D) Orin |
optionA |
| Awon Ilorin lo ni |
A) ifa B) obeke C) Ṣẹwẹlẹ D) Olofa |
optionC |
| 80 ni ede Yoruba |
A) ọgọfa B) ọgọrin C) ọgọjọ D) aadọrin |
optionB |
| Ayẹyẹ ti won maa n se ni ilẹ Yoruba ni |
A) akara oyinbo B) kọọtu C) ẹrin D) igbeyawo |
optionD |
| Awon ______ lo maa n sere bojuboju |
A) ọmọde B) ọkunrin C) obinrin D) arugbo |
optionA |
| Awon ẸGBA lo n kọ |
A) ijala B) ege C) iyere D) Orin oro |
optionB |
| JSS THREE YORUBA: Ni abule Ipake lẹba Igbogun, awon ore meta kan wa: Ajani, Eyinafe ati Taofeek. Ise agbe ni won n se. Oko won ko si jina sira. Ni ojo kan, Taofeek lo si Ile Ajani ni oke oko, won ki ara won, o si so fun Ajani pe oun fe ya awon agbado oko oun tori pe won ti gbo, o te siwaju pe oun fe lo ta won ni ọja Ifọ ki oun le ri owo idanwo BECE Kafaya, omo oun san. Bi inu ti ri lobi n yan, Ajani da Taofeek lohun. O sọ pe oun alara fẹ wa si ile re lati wa so fun-un pe oun fero oko o |
A) Ipake B) Igbogun C) Ibogun D) Ifo |
optionC |
| 'O' ti won fala si ninu ayọka oke duro fun |
A) Ipake B) Ajani C) Eyinafe D) Taofeek |
optionD |
| Ta lo fe yẹ ona si oko re? |
A) Taofeek B) Ajani C) Eyinafe D) Ko si |
optionC |
| Kini idi ti Taofeek se fe lọ ta agabdo re? Lati __ |
A) fi ra nnkan loja B) fi ran Kafaya nile iwe C) fi jeun D) san owo idanwo |
optionD |
| Iruse asa wo lo suyọ ninu ayọka oke? Aṣa |
A) iranraẹnilọwọ B) ikomọjade C) ọmọ titọ D) iṣẹ ṣiṣe |
optionA |
| Orukọ miiran ti owo ṣiṣe n jẹ ni |
A) katakata B) oja tita C) ipolowo oja D) ipolongo |
optionA |
| Faweli iwaju ni |
A) o B) a C) i D) u |
optionC |
| Oja ti awon Yoruba maa n polowo pe "Ye ọbẹ! ni |
A) eja B) eran C) igi D) adie |
optionB |
| Orukọ ti won maa n pe obinrin ti ko rọmọbi ni ile Yoruba ni |
A) abiamọ B) abiye C) Abirun D) agan |
optionD |
| Fawelo aarin ni |
A) a B) ọ C) u D) I |
optionA |
| Feweli meloo lo wa ninu ede Yoruba? |
A) mewaa B) mejila C) meji D) mẹjọ |
optionB |
| _____ lo maa n rọ ọkọ ati ada |
A) Alagbẹdẹ B) Gbẹnagbẹna C) Agbẹ D) Ọdẹ |
optionB |
| Ọrọ orukọ ni ede Geesi ni |
A) name B) noun C) pronoun D) proper |
optionB |
| Igbesẹ akọkọ ninu itọju alaboyun ni ode oni ni |
A) yiya aworan oyun B) ayewo eje C) Fifi orukọ sile nile iwosan D) kiko eru omo lo si Ile owosan |
optionD |
| Ọmọ o ni agbara lati wa si aye ati lati ku ni iye igba ti o wuu ni awon Yoruba n pe ni |
A) Abiku B) Awaye C) Abaya D) Abiye |
optionA |
| ____ ni won fi n tọju alaboyun ni atijọ |
A) egbogi B) abẹrẹ C) omi D) agbo |
optionA |
| 85 ni ede Yoruba ni |
A) aarun din lọgọrin B) aarunlelogorin C) eejolelaarun D) aarunlenigba |
optionB |
| Awon to n ta ọja pẹpẹpẹ bii bisikiiti, suuti ni won n pe ni |
A) oniworobo B) alarobọ C) ope D) karakata |
optionA |
| Awon to n ta ọja oko ni won n pe ki |
A) ara oko B) oloko C) oniwosiwosi D) alaroobọ |
optionD |
| ____ le fa airomobi |
A) ijo jupajupa B) arun C) orin D) ise sise |
optionA |